Native Bible

Hebrews 13:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹ̀lú gbogbo yín.

Hebrews 13:25 in English

Hebrews 13:25 · Berean Standard Bible

Grace be with all of you.*

Context

23Ẹ mọ pé a sá titu Timotiu arákùnrin wa sílẹ̀; bí ó ba tètè dé, èmí pẹ̀lú rẹ̀ yóò rí yín, àti gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. 24Ẹ ki gbogbo àwọn tí ń ṣe olórí yín, àti gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. Àwọn tí o ti Itali wá ki yín. 25Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹ̀lú gbogbo yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.