Native Bible

Genesis 6:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Noa sì ṣe ohun gbogbo bí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún un.

Genesis 6:22 in English

Genesis 6:22 · Berean Standard Bible

So Noah did everything precisely as God had commanded him.

Context

20Mú onírúurú àwọn ẹyẹ, ẹranko àti àwọn ohun tí ń rákò ní méjì méjì, kí a bá lè pa wọ́n mọ́ láààyè. 21Mú onírúurú oúnjẹ wá sínú ọkọ̀, kí o pa wọ́n mọ́ fún jíjẹ gbogbo ẹ̀yin tí ẹ wà nínú ọkọ̀ àti ènìyàn àti ẹranko.” 22Noa sì ṣe ohun gbogbo bí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún un.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.