Native Bible

Genesis 5:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Metusela pé igba ọdún dín mẹ́tàlá ní o bí Lameki.

Genesis 5:25 in English

Genesis 5:25 · Berean Standard Bible

When Methuselah was 187 years old, he became the father of Lamech.

Context

23Àpapọ̀ ọjọ́ Enoku sì jẹ́ irinwó ọdún dín márùndínlógójì (365). 24Enoku bá Ọlọ́run rìn; a kò sì rí i mọ́ nítorí Ọlọ́run mú un lọ. 25Nígbà tí Metusela pé igba ọdún dín mẹ́tàlá ní o bí Lameki. 26Lẹ́yìn èyí Metusela wà láààyè fún ẹgbẹ̀rin ọdún dín méjìdínlógún (782), lẹ́yìn ìgbà tí ó bí Lameki, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin. 27Àpapọ̀ ọdún Metusela jẹ́ ẹgbẹ̀rún ọdún dín mọ́kànlélọ́gbọ̀n (969), ó sì kú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.