Gẹnẹsisi 46:9
Genesis 46:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọkùnrin Reubeni: Hanoku, Pallu, Hesroni àti Karmi.
Genesis 46:9 in English
Genesis 46:9 · Berean Standard Bible
The sons of Reuben: Hanoch, Pallu, Hezron, and Carmi.
Context
7Ó kó àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin pẹ̀lú àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin pẹ̀lú àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ obìnrin, gbogbo irú-ọmọ rẹ̀ lọ sí Ejibiti. 8Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ Israẹli (Jakọbu àti ìran rẹ̀) tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ Ejibiti:
Reubeni àkọ́bí Jakọbu. 9Àwọn ọmọkùnrin Reubeni:
Hanoku, Pallu, Hesroni àti Karmi. 10Àwọn ọmọkùnrin Simeoni:
Jemueli, Jamini, Ohadi, Jakini, Sohari àti Saulu, tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọbìnrin ará Kenaani. 11Àwọn ọmọkùnrin Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.