Gẹnẹsisi 46:13
Genesis 46:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọkùnrin: Isakari! Tola, Pua, Jaṣibu àti Ṣimroni.
Genesis 46:13 in English
Genesis 46:13 · Berean Standard Bible
The sons of Issachar: Tola, Puvah,* Job,* and Shimron.
Context
11Àwọn ọmọkùnrin Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari. 12Àwọn ọmọkùnrin Juda:
Eri, Onani, Ṣela, Peresi àti Sera (ṣùgbọ́n Ẹri àti Onani ti kú ní ilẹ̀ Kenaani).
Àwọn ọmọ Peresi:
Hesroni àti Hamulu. 13Àwọn ọmọkùnrin: Isakari!
Tola, Pua, Jaṣibu àti Ṣimroni. 14Àwọn ọmọkùnrin Sebuluni:
Seredi, Eloni àti Jahaleli. 15Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin Lea tí ó bí fún Jakọbu ní Padani-Aramu yàtọ̀ fún Dina ọmọbìnrin rẹ̀. Àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ àti ọmọbìnrin rẹ̀ wọ̀nyí jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) lápapọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.