Gẹnẹsisi 42:1
Genesis 42:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà tí Jakọbu mọ̀ pé ọkà wà ní Ejibiti, ó wí fún àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin pé, “Èéṣe tí ẹ ń wo ara yín lásán?”
Genesis 42:1 in English
Genesis 42:1 · Berean Standard Bible
When Jacob learned that there was grain in Egypt, he said to his sons, “Why are you staring at one another?”
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.