Gẹnẹsisi 36:9
Genesis 36:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èyí ni ìran Esau baba àwọn ará Edomu ní àwọn orílẹ̀-èdè olókè Seiri.
Genesis 36:9 in English
Genesis 36:9 · Berean Standard Bible
This is the account of Esau, the father of the Edomites, in the area of Mount Seir.
Context
7Ohun ìní wọn pọ̀ ju èyí tí àwọn méjèèjì lè máa gbé ní ojú kan lọ. Ilẹ̀ tí wọ́n wà kò le gba àwọn méjèèjì nítorí àwọn ohun ọ̀sìn wọn. 8Báyìí ni Esau (tí a tún mọ̀ sí Edomu) tẹ̀dó sí àwọn orílẹ̀-èdè olókè tí Seiri. 9Èyí ni ìran Esau baba àwọn ará Edomu ní àwọn orílẹ̀-èdè olókè Seiri. 10Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Esau:
Elifasi ọmọ Adah aya Esau àti Reueli, ọmọ Basemati tí í ṣe aya Esau pẹ̀lú. 11Àwọn ọmọ Elifasi ni ìwọ̀nyí:
Temani, Omari, Sefi, Gatamu, àti Kenasi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.