Gẹnẹsisi 36:3
Genesis 36:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sì tún fẹ́ Basemati ọmọ Iṣmaeli arábìnrin Nebaioti.
Genesis 36:3 in English
Genesis 36:3 · Berean Standard Bible
and Basemath daughter of Ishmael and sister of Nebaioth.
Context
1Wọ̀nyí ni ìran Esau, ẹni tí a ń pè ní Edomu. 2Nínú àwọn ọmọbìnrin Kenaani ni Esau ti fẹ́ àwọn ìyàwó rẹ̀: Adah ọmọbìnrin Eloni ará Hiti àti Oholibama, ọmọbìnrin Ana, ọmọ ọmọ Sibeoni ará Hifi. 3Ó sì tún fẹ́ Basemati ọmọ Iṣmaeli arábìnrin Nebaioti. 4Adah bí Elifasi fún Esau, Basemati sì bí Reueli, 5Oholibama pẹ̀lú sì bí Jeuṣi, Jalamu, àti Kora. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ tí Esau bí ní Kenaani.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.