Native Bible

Genesis 36:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani.

Genesis 36:22 in English

Genesis 36:22 · Berean Standard Bible

The sons of Lotan were Hori and Hemam.* Timna was Lotan’s sister.

Context

20Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Seiri ará Hori tí ó ń gbé ní ilẹ̀ náà: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, 21Diṣoni, Eseri, àti Diṣani, àwọn wọ̀nyí olórí ènìyàn Hori, àwọn ọmọ Seiri ni ilẹ̀ Edomu. 22Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani. 23Àwọn ọmọ Ṣobali: Alifani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti Onamu. 24Àwọn ọmọ Sibeoni: Aiah àti Ana. Èyí ni Ana tí ó rí ìsun omi gbígbóná ní inú aginjù bí ó ti ń da àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Ṣebeoni baba rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.