Gẹnẹsisi 33:20
Genesis 33:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Níbẹ̀ ni ó gbé tẹ́ pẹpẹ kan tí ó pè ní El Elohe Israẹli. * 33.20 tí ó túmọ̀ sí, Ọlọ́run Israẹli
Genesis 33:20 in English
Genesis 33:20 · Berean Standard Bible
There he set up an altar and called it El-Elohe-Israel.*
Context
18Lẹ́yìn ìgbà tí Jakọbu tí Padani-Aramu dé, àlàáfíà ni Jakọbu dé ìlú Ṣekemu ní ilẹ̀ Kenaani, ó sì pàgọ́ sí itòsí ìlú náà. 19Ó sì ra ilẹ̀ kan tí ó pàgọ́ sí ni ọgọ́rùn-ún owó fàdákà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hamori tí í ṣe baba Ṣekemu. 20Níbẹ̀ ni ó gbé tẹ́ pẹpẹ kan tí ó pè ní El Elohe Israẹli. *
33.20 tí ó túmọ̀ sí, Ọlọ́run Israẹli
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.