Gẹnẹsisi 26:35
Genesis 26:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Fífẹ́ tí a fẹ́ àwọn obìnrin wọ̀nyí jẹ́ ìbànújẹ́ fún Isaaki àti Rebeka. 26.21 tí ó túmọ̀ sí kànga àtakò 26.33 tí ó túmọ̀ sí, kànga májẹ̀mú
Genesis 26:35 in English
Genesis 26:35 · Berean Standard Bible
And they brought grief to Isaac and Rebekah.
Context
33Ó sì pe orúkọ kànga náà ní Ṣiba, * títí di òní olónìí, orúkọ ìlú náà ni Beerṣeba. 34Nígbà tí Esau pé ọmọ ogójì ọdún ó fẹ́ ọmọbìnrin kan tí a ń pè ní Juditi, ọmọ Beeri, ará Hiti, ó sì tún fẹ́ Basemati, ọmọ Eloni ará Hiti. 35Fífẹ́ tí a fẹ́ àwọn obìnrin wọ̀nyí jẹ́ ìbànújẹ́ fún Isaaki àti Rebeka.
26.21 tí ó túmọ̀ sí kànga àtakò
26.33 tí ó túmọ̀ sí, kànga májẹ̀mú
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.