Native Bible

Genesis 25:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema.

Genesis 25:15 in English

Genesis 25:15 · Berean Standard Bible

Hadad, Tema, Jetur, Naphish, and Kedemah.

Context

13Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Iṣmaeli bí a ṣe bí wọn, bẹ̀rẹ̀ láti orí: Nebaioti àkọ́bí, Kedari, Adbeeli, Mibsamu, 14Miṣima, Duma, Massa, 15Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema. 16Wọ̀nyí sì ni orúkọ àwọn ọmọ Iṣmaeli, wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọba méjìlá gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn. 17Àpapọ̀ ọdún tí Iṣmaeli lò láyé jẹ́ ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.