Gẹnẹsisi 23:12
Genesis 23:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Abrahamu sì tún tẹríba níwájú àwọn ènìyàn ìlú náà,
Genesis 23:12 in English
Genesis 23:12 · Berean Standard Bible
Again Abraham bowed down before the people of the land
Context
10Efroni ará Hiti sì wà níbẹ̀ pẹ̀lú, ó sì dá Abrahamu lóhùn lójú gbogbo àwọn ará ìlú tí ó wà níbẹ̀, lẹ́nu ibodè ìlú, 11pé, “Rárá, olúwa mi. Gbọ́ tèmi; mo fún ọ ní ilẹ̀ náà àti ihò àpáta tí ó wà níbẹ̀. Mo fún ọ níwájú gbogbo àwọn ènìyàn mi. Sin òkú rẹ síbẹ̀.” 12Abrahamu sì tún tẹríba níwájú àwọn ènìyàn ìlú náà, 13ó sì wí fún Efroni lójú gbogbo wọn pé, “Bí ìwọ bá fẹ́, gbọ́ tèmi, èmi yóò san owó ilẹ̀ náà, gbà á lọ́wọ́ mi kí n lè sin òkú mi síbẹ̀.” 14Efroni sì dá Abrahamu lóhùn pé,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.