Native Bible

Genesis 22:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àlè rẹ̀ tí ń jẹ́ Reuma náà bí àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí fun un: Teba, Gahamu, Tahasi àti Maaka. 22.14 Jehofah Jire tí ó túmọ̀ sí, Olúwa Yóò Pèsè

Genesis 22:24 in English

Genesis 22:24 · Berean Standard Bible

Moreover, Nahor’s concubine, whose name was Reumah, bore Tebah, Gaham, Tahash, and Maacah.

Context

22Kesedi, Haso, Pildasi, Jidlafi, àti Betueli.” 23Betueli sì ni baba Rebeka. Milka sì bí àwọn ọmọ mẹ́jọ wọ̀nyí fún Nahori arákùnrin Abrahamu. 24Àlè rẹ̀ tí ń jẹ́ Reuma náà bí àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí fun un: Teba, Gahamu, Tahasi àti Maaka. 22.14 Jehofah Jire tí ó túmọ̀ sí, Olúwa Yóò Pèsè

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.