Gẹnẹsisi 22:23
Genesis 22:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Betueli sì ni baba Rebeka. Milka sì bí àwọn ọmọ mẹ́jọ wọ̀nyí fún Nahori arákùnrin Abrahamu.
Genesis 22:23 in English
Genesis 22:23 · Berean Standard Bible
And Bethuel became the father of Rebekah. Milcah bore these eight sons to Abraham’s brother Nahor.
Context
21Usi àkọ́bí rẹ̀, Busi arákùnrin rẹ̀,
Kemueli (baba Aramu). 22Kesedi, Haso, Pildasi, Jidlafi, àti Betueli.” 23Betueli sì ni baba Rebeka.
Milka sì bí àwọn ọmọ mẹ́jọ wọ̀nyí fún Nahori arákùnrin Abrahamu. 24Àlè rẹ̀ tí ń jẹ́ Reuma náà bí àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí fun un:
Teba, Gahamu, Tahasi àti Maaka.
22.14 Jehofah Jire tí ó túmọ̀ sí, Olúwa Yóò Pèsè
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.