Native Bible

Genesis 17:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àti gbogbo ọkùnrin tí ó wà ní ilé Abrahamu, ìbá à ṣe èyí tí a bí ní ilé rẹ̀ tàbí èyí tí a fi owó rà lọ́wọ́ àlejò ni a kọ ní ilà pẹ̀lú rẹ̀. 17.1 tí ó túmọ̀ sí, El-Ṣaddai

Genesis 17:27 in English

Genesis 17:27 · Berean Standard Bible

And all the men of Abraham’s household—both servants born in his household and those purchased from foreigners—were circumcised with him.

Context

25Iṣmaeli ọmọ rẹ̀ jẹ́ ẹni ọdún mẹ́tàlá. 26Ní ọjọ́ náà gan an ni a kọ Abrahamu ní ilà pẹ̀lú Iṣmaeli ọmọ rẹ̀ ọkùnrin. 27Àti gbogbo ọkùnrin tí ó wà ní ilé Abrahamu, ìbá à ṣe èyí tí a bí ní ilé rẹ̀ tàbí èyí tí a fi owó rà lọ́wọ́ àlejò ni a kọ ní ilà pẹ̀lú rẹ̀. 17.1 tí ó túmọ̀ sí, El-Ṣaddai

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.