Native Bible

Genesis 11:32 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Tẹra pé ọmọ igba ọdún ó lé márùn-ún (205) ni ó kú ní Harani. 11.2 tí ó túmọ̀ sí, Babeli 11.4 tí ó túmọ̀ sí, òkìkí 11.9 Èyí ní Babiloni; Babeli ni èdé Heberu tí a mọ̀ sí ìdàrúdàpọ̀.

Genesis 11:32 in English

Genesis 11:32 · Berean Standard Bible

Terah lived 205 years, and he died in Haran.

Context

30Sarai sì yàgàn, kò sì bímọ. 31Tẹra sì mú ọmọ rẹ̀ Abramu àti Lọti ọmọ Harani, ọmọ ọmọ rẹ̀, ó sì mú Sarai tí i ṣe aya ọmọ rẹ̀. Abramu pẹ̀lú gbogbo wọn sì jáde kúrò ní Uri ti Kaldea láti lọ sí ilẹ̀ Kenaani. Ṣùgbọ́n nígbà tí wọn dé Harani wọ́n tẹ̀dó síbẹ̀. 32Nígbà tí Tẹra pé ọmọ igba ọdún ó lé márùn-ún (205) ni ó kú ní Harani. 11.2 tí ó túmọ̀ sí, Babeli 11.4 tí ó túmọ̀ sí, òkìkí 11.9 Èyí ní Babiloni; Babeli ni èdé Heberu tí a mọ̀ sí ìdàrúdàpọ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.