Gẹnẹsisi 10:13
Genesis 10:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu.
Genesis 10:13 in English
Genesis 10:13 · Berean Standard Bible
Mizraim was the father of the Ludites, the Anamites, the Lehabites, the Naphtuhites,
Context
11Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí Asiria, níbi tí ó ti tẹ ìlú Ninefe, Rehoboti àti Kala, 12àti Resini, tí ó wà ní àárín Ninefe àti Kala, tí ó jẹ́ ìlú olókìkí. 13Ejibiti sì bí
Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu. 14Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu. 15Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀,
àti Heti.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.