Native Bible

Galatians 1:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo nítorí mi.

Galatians 1:24 in English

Galatians 1:24 · Berean Standard Bible

And they glorified God because of me.

Context

22Mo sì jẹ́ ẹni tí a kò mọ̀ lójú fún àwọn ìjọ tí ó wà nínú Kristi ni Judea. 23Wọ́n kàn gbọ́ ìròyìn wí pé, “Ẹni tí ó tí ń ṣe inúnibíni sí wa rí, ní ìsinsin yìí ti ń wàásù ìgbàgbọ́ náà tí ó ti gbìyànjú láti bàjẹ́ nígbà kan rí.” 24Wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo nítorí mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.