Native Bible

Ezekiel 27:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Ọmọ ènìyàn, pohùnréré ẹkún fún Tire.

Ezekiel 27:2 in English

Ezekiel 27:2 · Berean Standard Bible

“Now you, son of man, take up a lament for Tyre.

Context

1Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé: 2“Ọmọ ènìyàn, pohùnréré ẹkún fún Tire. 3Sọ fún Tire, tí a tẹ̀dó sí ẹnu-bodè Òkun, oníṣòwò àwọn orílẹ̀-èdè fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù. ‘Èyí yìí ní Olúwa Olódùmarè wí: “ ‘Ìwọ Tire wí pé, “Ẹwà mi pé.” 4Ààlà rẹ wà ní àárín Òkun; àwọn ọ̀mọ̀lé rẹ ti mú ẹwà rẹ pé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.