Native Bible

Ezekiel 14:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Díẹ̀ nínú àwọn àgbàgbà Israẹli wá sọ́dọ̀ mi, wọ́n sì jókòó níwájú mi.

Ezekiel 14:1 in English

Ezekiel 14:1 · Berean Standard Bible

Then some of the elders of Israel came and sat down before me.

Context

1Díẹ̀ nínú àwọn àgbàgbà Israẹli wá sọ́dọ̀ mi, wọ́n sì jókòó níwájú mi. 2Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá, 3“Ọmọ ènìyàn, àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ti gbé òrìṣà kalẹ̀ sínú ọkàn wọn, wọ́n sì gbé àwọn ohun tó lè mú wọn ṣubú sínú ẹ̀ṣẹ̀ síwájú wọn; Èmi yóò ha jẹ́ kí wọ́n béèrè lọ́wọ́ mi rárá bí?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.