Eksodu 39:13
Exodus 39:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ní ipele kẹrin, karisoliti, óníkìsì, àti jasperi. Ó sì tò wọ́n ní ojú ìdè wúrà ní títò wọn.
Exodus 39:13 in English
Exodus 39:13 · Berean Standard Bible
and the fourth row had a beryl, an onyx, and a jasper. These stones were mounted in gold filigree settings.
Context
11ní ipele kejì, turikuose, safire, emeradi àti diamọndi; 12ní ipele kẹta, jasiniti, agate àti ametisiti; 13ní ipele kẹrin, karisoliti, óníkìsì, àti jasperi. Ó sì tò wọ́n ní ojú ìdè wúrà ní títò wọn. 14Wọ́n jẹ́ òkúta méjìlá, ọ̀kan fún orúkọ àwọn ọmọ Israẹli kọ̀ọ̀kan, a fín ọ̀kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí èdìdì pẹ̀lú orúkọ ẹnìkọ̀ọ̀kan ẹ̀yà méjèèjìlá. 15Fún ìgbàyà náà, wọ́n ṣe ẹ̀wọ̀n iṣẹ́ kìkì wúrà, gẹ́gẹ́ bi okùn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.