Eksodu 39:12
Exodus 39:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ní ipele kẹta, jasiniti, agate àti ametisiti;
Exodus 39:12 in English
Exodus 39:12 · Berean Standard Bible
the third row had a jacinth, an agate, and an amethyst;
Context
10Ó sì to ipele òkúta oníyebíye mẹ́rin sí i. Ní ipele kìn-ín-ní ní rúbì wà, topasi àti berili; 11ní ipele kejì, turikuose, safire, emeradi àti diamọndi; 12ní ipele kẹta, jasiniti, agate àti ametisiti; 13ní ipele kẹrin, karisoliti, óníkìsì, àti jasperi. Ó sì tò wọ́n ní ojú ìdè wúrà ní títò wọn. 14Wọ́n jẹ́ òkúta méjìlá, ọ̀kan fún orúkọ àwọn ọmọ Israẹli kọ̀ọ̀kan, a fín ọ̀kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí èdìdì pẹ̀lú orúkọ ẹnìkọ̀ọ̀kan ẹ̀yà méjèèjìlá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.