Native Bible

Exodus 35:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

òkúta óníkìsì àti òkúta tí a tò sí ẹ̀wù efodu àti ìgbàyà.

Exodus 35:9 in English

Exodus 35:9 · Berean Standard Bible

and onyx stones and gemstones to be mounted on the ephod and breastpiece.

Context

7awọ àgbò tí a kùn ní pupa àti awọ màlúù; odò igi kasia; 8òróró olifi fún títan iná; olóòórùn fún òróró ìtasórí, àti fún tùràrí dídùn; 9òkúta óníkìsì àti òkúta tí a tò sí ẹ̀wù efodu àti ìgbàyà. 10“Gbogbo ẹni tí ó ní ọgbọ́n láàrín yín, kí ó wa, kí ó sì wá ṣe gbogbo ohun tí Olúwa ti pàṣẹ: 11“àgọ́ náà pẹ̀lú àgọ́ rẹ àti ìbòrí rẹ̀, kọ́kọ́rọ́ rẹ̀, pákó rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, ọ̀wọ́n rẹ̀ àti ihò ìtẹ̀bọ̀ rẹ̀;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.