Native Bible

Exodus 31:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Wò ó, Èmi ti yan Besaleli ọmọ Uri, ọmọ Huri, ti ẹ̀yà Juda,

Exodus 31:2 in English

Exodus 31:2 · Berean Standard Bible

“See, I have called by name Bezalel son of Uri, the son of Hur, of the tribe of Judah.

Context

1Olúwa wí fún Mose pé, 2“Wò ó, Èmi ti yan Besaleli ọmọ Uri, ọmọ Huri, ti ẹ̀yà Juda, 3Èmi sì ti fi Ẹ̀mí Ọlọ́run kún un pẹ̀lú ọgbọ́n, òye àti ìmọ̀ ní gbogbo onírúurú iṣẹ́ ọnà. 4Láti ṣe aláràbarà iṣẹ́ ní wúrà, fàdákà àti idẹ,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.