Native Bible

Exodus 26:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìwọ ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà,

Exodus 26:18 in English

Exodus 26:18 · Berean Standard Bible

Construct twenty frames for the south side of the tabernacle,

Context

16Kí pákó kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ní fífẹ̀. 17Pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì ni kí ó kọjú sí ara wọn. Ṣe gbogbo àwọn pákó àgọ́ náà bí èyí. 18Ìwọ ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà, 19ìwọ ó sì ṣe ogójì ìhà ìtẹ̀bọ̀ fàdákà kí ó lọ sí ìsàlẹ̀ wọn. Méjì fún pákó kọ̀ọ̀kan, ọ̀kan ní ìsàlẹ̀ ìtẹ̀bọ̀ kọ̀ọ̀kan. 20Àti ìhà kejì, ni ìhà àríwá àgọ́ náà, ṣe ogún pákó síbẹ̀

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.