Eksodu 26:17
Exodus 26:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì ni kí ó kọjú sí ara wọn. Ṣe gbogbo àwọn pákó àgọ́ náà bí èyí.
Exodus 26:17 in English
Exodus 26:17 · Berean Standard Bible
Two tenons * must be connected to each other for each frame. Make all the frames of the tabernacle in this way.
Context
15“Ìwọ ó sì ṣe pákó igi kasia tí ó dúró òró fún àgọ́ náà. 16Kí pákó kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ní fífẹ̀. 17Pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì ni kí ó kọjú sí ara wọn. Ṣe gbogbo àwọn pákó àgọ́ náà bí èyí. 18Ìwọ ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà, 19ìwọ ó sì ṣe ogójì ìhà ìtẹ̀bọ̀ fàdákà kí ó lọ sí ìsàlẹ̀ wọn. Méjì fún pákó kọ̀ọ̀kan, ọ̀kan ní ìsàlẹ̀ ìtẹ̀bọ̀ kọ̀ọ̀kan.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.