Eksodu 20:13
Exodus 20:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ kò gbọdọ̀ pànìyàn.
Exodus 20:13 in English
Exodus 20:13 · Berean Standard Bible
You shall not murder.*
Context
11Nítorí ní ọjọ́ mẹ́fà ni Olúwa dá ọ̀run àti ayé, òkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn, ó sì sinmi ní ọjọ́ keje: nítorí náà ni Olúwa ṣe bùkún ọjọ́ ìsinmi tí ó sì yà á sí mímọ́. 12Bọ̀wọ̀ fún baba òun ìyá rẹ, kí ọjọ́ rẹ kí ó lè pẹ́ ní orí ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ. 13Ìwọ kò gbọdọ̀ pànìyàn. 14Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe panṣágà. 15Ìwọ kò gbọdọ̀ jalè.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.