Eksodu 15:12
Exodus 15:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ìwọ na apá ọ̀tún rẹ, ilẹ̀ si gbé wọn mì.
Exodus 15:12 in English
Exodus 15:12 · Berean Standard Bible
You stretched out Your right hand, and the earth swallowed them up.
Context
10Ìwọ fẹ́ èémí rẹ,
òkun ru bò wọ́n mọ́lẹ̀.
Wọ́n rì bí òjé
ni àárín omi ńlá. 11Ta ni nínú àwọn òrìṣà
tó dàbí rẹ, Olúwa?
Ta ló dàbí rẹ:
ní títóbi,
ní mímọ́ Ẹlẹ́rù ni yìn,
tí ń ṣe ohun ìyanu? 12“Ìwọ na apá ọ̀tún rẹ,
ilẹ̀ si gbé wọn mì. 13Nínú ìfẹ́ rẹ ti kì í sákí Ìwọ ṣe amọ̀nà
àwọn ènìyàn náà tí Ìwọ ti rà padà.
Nínú agbára rẹ Ìwọ yóò tọ́ wọn,
lọ sí ibi ìjókòó rẹ mímọ́. 14Orílẹ̀-èdè yóò gbọ́ wọn yóò wárìrì.
Ìkáàánú yóò mi àwọn ènìyàn Filistia.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.