Eksodu 12:45
Exodus 12:45 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ṣùgbọ́n àtìpó àti alágbàṣe kò ni jẹ nínú rẹ̀.
Exodus 12:45 in English
Exodus 12:45 · Berean Standard Bible
A temporary resident or hired hand shall not eat the Passover.
Context
43Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé, “Ìwọ̀n yìí ni àwọn òfin fún àjọ ìrékọjá:
“Àjèjì kò gbọdọ̀ jẹ nínú rẹ̀. 44Ẹrú tí ẹ̀yin bá rà lè jẹ́ nínú rẹ̀ lẹ́yìn tí ẹ̀yin bá ti kọ ọ́ ní ilà, 45ṣùgbọ́n àtìpó àti alágbàṣe kò ni jẹ nínú rẹ̀. 46“Nínú ilé ni ẹ ti gbọdọ̀ jẹ ẹ́; ẹ kò gbọdọ̀ mú èyíkéyìí nínú ẹran náà jáde kúrò nínú ilé. Ẹ má ṣe ṣẹ́ ọ̀kankan nínú egungun rẹ̀. 47Gbogbo àjọ Israẹli ni ó gbọdọ̀ ṣe àjọyọ̀ ọ rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.