Esteri 9:8
Esther 9:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Porata, Adalia, Aridata,
Esther 9:8 in English
Esther 9:8 · Berean Standard Bible
Poratha, Adalia, Aridatha,
Context
6Ní ilé ìṣọ́ ti Susa, àwọn Júù pa ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ọkùnrin run. 7Wọ́n sì tún pa Parṣandata, Dalfoni, Aspata, 8Porata, Adalia, Aridata, 9Parmaṣta, Arisai, Aridai àti Faisata. 10Àwọn ọmọkùnrin mẹ́wẹ̀ẹ̀wá tí wọ́n jẹ́ ọmọ Hamani, ọmọ Hammedata, ọ̀tá àwọn Júù. Ṣùgbọ́n wọn kò fi ọwọ́ wọn lé ìkógun un wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.