Efesu 6:3
Ephesians 6:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“ki ó lé dára fún ọ, àti kí ìwọ lè wà pẹ́ ní ayé.”
Ephesians 6:3 in English
Ephesians 6:3 · Berean Standard Bible
“that it may go well with you and that you may have a long life on the earth.”*
Context
1Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ tí àwọn òbí i yín nínú Olúwa, nítorí pé èyí ní ó tọ́. 2“Bọ̀wọ̀ fún baba àti ìyá rẹ,” èyí tí í ṣe òfin kìn-ín-ní pẹ̀lú ìlérí, 3“ki ó lé dára fún ọ, àti kí ìwọ lè wà pẹ́ ní ayé.” 4Àti ẹ̀yin baba, ẹ má ṣe mú àwọn ọmọ yín bínú, ṣùgbọ́n ẹ máa tọ́ wọn nínú ẹ̀kọ́ àti ìkìlọ̀ Olúwa. 5Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ máa gbọ́ ti àwọn olúwa yín nípá ti ara, pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, bí ẹni pé sí Kristi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.