Native Bible

Ephesians 6:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ tí àwọn òbí i yín nínú Olúwa, nítorí pé èyí ní ó tọ́.

Ephesians 6:1 in English

Ephesians 6:1 · Berean Standard Bible

Children, obey your parents in the Lord, for this is right.

Context

1Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ tí àwọn òbí i yín nínú Olúwa, nítorí pé èyí ní ó tọ́. 2“Bọ̀wọ̀ fún baba àti ìyá rẹ,” èyí tí í ṣe òfin kìn-ín-ní pẹ̀lú ìlérí, 3“ki ó lé dára fún ọ, àti kí ìwọ lè wà pẹ́ ní ayé.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.