Native Bible

Ecclesiastes 3:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo ti rí àjàgà tí Ọlọ́run gbé lé ọmọ ènìyàn.

Ecclesiastes 3:10 in English

Ecclesiastes 3:10 · Berean Standard Bible

I have seen the burden that God has laid upon the sons of men to occupy them.

Context

8ìgbà láti ní ìfẹ́ àti ìgbà láti kórìíra ìgbà fún ogun àti ìgbà fún àlàáfíà. 9Kí ni òṣìṣẹ́ jẹ ní èrè nínú wàhálà rẹ̀? 10Mo ti rí àjàgà tí Ọlọ́run gbé lé ọmọ ènìyàn. 11Ó ti ṣe ohun gbogbo dáradára ní àsìkò tirẹ̀, ó sì ti fi èrò nípa ayérayé sí ọkàn ọmọ ènìyàn, síbẹ̀, wọn kò le ṣe àwárí ìdí ohun tí Ọlọ́run ti ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin. 12Mo mọ̀ wí pé kò sí ohun tí ó dára fún ènìyàn ju pé kí inú wọn dùn kí wọn sì ṣe rere níwọ̀n ìgbà tí wọ́n sì wà láààyè.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.