Native Bible

Deuteronomy 5:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ́rìí èké sí ẹnìkejì rẹ.

Deuteronomy 5:20 in English

Deuteronomy 5:20 · Berean Standard Bible

You shall not bear false witness against your neighbor.*

Context

18Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe panṣágà. 19Ìwọ kò gbọdọ̀ jalè. 20Ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ́rìí èké sí ẹnìkejì rẹ. 21Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ojúkòkòrò sí aya ẹnìkéjì rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ojúkòkòrò sí ilé ẹnìkéji rẹ, oko rẹ̀, àti ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ ọkùnrin, àti ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin, akọ màlúù rẹ̀ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, àti ohun gbogbo tí í ṣe ti ẹnìkéji rẹ.” 22Wọ̀nyí ni àwọn àṣẹ Olúwa tí a kéde rẹ̀ sí gbogbo ìpéjọpọ̀ ọ yín, níbẹ̀ ní orí òkè, láàrín iná, ìkùùkuu àti òkùnkùn biribiri, kò sì fi ohunkóhun kún un mọ́. Ó sì kọ wọ́n sínú wàláà méjì, Ó sì fi wọ́n lé mi lọ́wọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.