Deuteronomi 32:35
Deuteronomy 32:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ti èmi ni láti gbẹ̀san. Èmi yóò san án fún wọn ní àkókò tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn yóò yọ; ọjọ́ ìdààmú wọn súnmọ́ etílé ohun tí ó sì ń bọ̀ wá bá wọn yára bọ̀.”
Deuteronomy 32:35 in English
Deuteronomy 32:35 · Berean Standard Bible
Vengeance is Mine; I will repay.* In due time their foot will slip; for their day of disaster is near, and their doom is coming quickly.”
Context
33Ọtí wáìnì wọn ìwọ ti dragoni ni,
àti oró mímú ti ejò paramọ́lẹ̀. 34“Èmi kò to èyí jọ ní ìpamọ́
èmi kò sì fi èdìdì dì í ní ìṣúra mi? 35Ti èmi ni láti gbẹ̀san. Èmi yóò san án fún wọn
ní àkókò tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn yóò yọ;
ọjọ́ ìdààmú wọn súnmọ́ etílé
ohun tí ó sì ń bọ̀ wá bá wọn yára bọ̀.” 36Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn an rẹ̀
yóò sì ṣàánú fún àwọn ìránṣẹ́ ẹ rẹ̀
nígbà tí ó bá rí i pé agbára wọn lọ tán
tí kò sì sí ẹnìkan tí ó kù, ẹrú tàbí ọmọ. 37Yóò wí pé, “Òrìṣà wọn dà báyìí,
àpáta tí wọ́n fi ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé e wọn,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.