Native Bible

Deuteronomy 2:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà náà ni a yípadà, tí a sì mú ọ̀nà wa pọ̀n lọ sí aginjù, a gba ọ̀nà Òkun Pupa, bí Olúwa ti darí mi. Ìgbà pípẹ́ ni a fi ń rìn kiri yíká agbègbè àwọn ìlú olókè Seiri.

Deuteronomy 2:1 in English

Deuteronomy 2:1 · Berean Standard Bible

Then we turned back and headed for the wilderness by way of the Red Sea,* as the LORD had instructed me, and for many days we wandered around Mount Seir.

Context

1Nígbà náà ni a yípadà, tí a sì mú ọ̀nà wa pọ̀n lọ sí aginjù, a gba ọ̀nà Òkun Pupa, bí Olúwa ti darí mi. Ìgbà pípẹ́ ni a fi ń rìn kiri yíká agbègbè àwọn ìlú olókè Seiri. 2Nígbà náà ni Olúwa sọ fún mi pé, 3“Ẹ ti rìn yí agbègbè ilẹ̀ olókè yìí pẹ́ tó, nísinsin yìí, ẹ yípadà sí ìhà àríwá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.