Ìṣe àwọn Aposteli 23:25
Acts 23:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sì kọ ìwé kan báyìí pé,
Acts 23:25 in English
Acts 23:25 · Berean Standard Bible
And he wrote the following letter:
Context
23Ó sì pe méjì nínú àwọn balógun ọ̀run sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, “Ẹ múra igba ọmọ-ogun sílẹ̀, láti lọ sí Kesarea, àti àádọ́rin ẹlẹ́ṣin, àti igba ọlọ́kọ̀, ní wákàtí kẹta òru. 24Ó sì wí pé, kí wọn pèsè ẹṣin, kí wọ́n gbé Paulu gùn ún; kí wọ́n sì lè mú un dé ọ̀dọ̀ Feliksi baálẹ̀ ní àlàáfíà.” 25Ó sì kọ ìwé kan báyìí pé, 26Kilaudiu Lisia,
sí Feliksi baálẹ̀ ọlọ́lá jùlọ,
àlàáfíà. 27Àwọn Júù mú ọkùnrin yìí, wọ́n sì ń pète láti pa á, nígbà náà ni mo dé pẹ̀lú ogun, mo sì gbà á lọ́wọ́ wọn nígbà tí mo gbọ́ pé ará Romu ni í ṣe.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.