2 Samuẹli 22:8
2 Samuel 22:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ilẹ̀ sì mì, ó sì wárìrì; ìpìlẹ̀ ọ̀run wárìrì, ó sì mì, nítorí tí ó bínú.
2 Samuel 22:8 in English
2 Samuel 22:8 · Berean Standard Bible
Then the earth shook and quaked; the foundations of the heavens * trembled; they were shaken because He burned with anger.
Context
6Ọ̀já isà òkú yí mi káàkiri;
ìkẹ́kùn ikú dojúkọ mí. 7“Nínú ìpọ́njú mi, èmi ké pé Olúwa,
èmi sì gbé ohùn mi sókè sí Ọlọ́run mi.
Ó sí gbóhùn mi láti tẹmpili rẹ̀
igbe mí wọ etí rẹ̀. 8Ilẹ̀ sì mì, ó sì wárìrì;
ìpìlẹ̀ ọ̀run wárìrì,
ó sì mì, nítorí tí ó bínú. 9Èéfín ti ihò imú rẹ̀ jáde wá,
iná ajónirun ti ẹnu rẹ̀ jáde wá,
ẹ̀yin iná bú jáde láti inú rẹ̀. 10Ó tẹ orí ọ̀run ba pẹ̀lú, ó sì sọ̀kalẹ̀;
òkùnkùn biribiri sì ń bẹ ní àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.