2 Samuẹli 22:2
2 Samuel 22:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sì wí pé, “Olúwa ni àpáta mi, àti Olùgbàlà mi;
2 Samuel 22:2 in English
2 Samuel 22:2 · Berean Standard Bible
He said: “The LORD is my rock, my fortress, and my deliverer.
Context
1Dafidi sì kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sí Olúwa ní ọjọ́ tí Olúwa gbà á kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ Saulu. 2Ó sì wí pé,
“Olúwa ni àpáta mi, àti Olùgbàlà mi; 3Ọlọ́run mi, àpáta mi, nínú ẹni tí èmi ní ààbò,
àti ìwo ìgbàlà mi, ibi ìsádi gíga mi.
Àti ibi ìlùmọ̀ mi, Olùgbàlà mi;
ìwọ ni ó ti gbà mí kúrò lọ́wọ́ ìwà ipá. 4“Èmi ké pe Olúwa, tí ó yẹ láti máa yìn,
ó sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.