Native Bible

2 John 1:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí òtítọ́ tí ń gbé inú wa, yóò sì bá wa gbé títí:

2 John 1:2 in English

2 John 1:2 · Berean Standard Bible

because of the truth that abides in us and will be with us forever:

Context

1Alàgbà, Sì àyànfẹ́ obìnrin ọlọ́lá àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn tí mo fẹ́ ní òtítọ́, kì í sì í ṣe èmi nìkan, ṣùgbọ́n gbogbo àwọn tí ó mọ òtítọ́ pẹ̀lú; 2nítorí òtítọ́ tí ń gbé inú wa, yóò sì bá wa gbé títí: 3Oore-ọ̀fẹ́, àánú, àti àlàáfíà, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba, àti láti ọ̀dọ̀ Jesu Kristi, Ọmọ Baba, yóò wà pẹ̀lú wa nínú òtítọ́ àti nínú ìfẹ́. 4Mo yọ̀ gidigidi pé mo rí nínú àwọn ọmọ rẹ tí ń rìn nínú òtítọ́, gẹ́gẹ́ bí Baba ti pa àṣẹ fún wa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.