2 Johanu 1:13
2 John 1:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ arábìnrin rẹ àyànfẹ́ kí ọ.
2 John 1:13 in English
2 John 1:13 · Berean Standard Bible
The children of your elect sister send you greetings.*
Context
11Nítorí ẹni tí ó bá kí kú ààbọ̀, ó ní ọwọ́ nínú iṣẹ́ búburú rẹ̀. 12Bí mo tilẹ̀ ní ohun púpọ̀ láti ṣe alábápín pẹ̀lú yín, síbẹ̀ èmi kò fẹ́ lo ìwé ìkọ̀wé àti jẹ́lú ìkọ̀wé. Ṣùgbọ́n èmi ní ìrètí láti tọ̀ yín wá àti láti bá a yín sọ̀rọ̀ lójúkojú, kí ayọ̀ yín bá à le è kún. 13Àwọn ọmọ arábìnrin rẹ àyànfẹ́ kí ọ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.