2 Kronika 15:19
2 Chronicles 15:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kò sí ogun mọ́ títí fún ọdún márùndínlógójì ti ìjọba Asa.
2 Chronicles 15:19 in English
2 Chronicles 15:19 · Berean Standard Bible
And there was no war until the thirty-fifth year of Asa’s reign.
Context
17Ṣùgbọ́n a kò mú àwọn ibi gíga náà kúrò ní Israẹli; síbẹ̀síbẹ̀ ọkàn Asa wà ní pípé ní ọjọ́ rẹ̀ gbogbo. 18Ó sì mú àwọn ohun mímọ́ náà ti baba rẹ̀ àti àwọn ohun mímọ́ ti òun tìkára rẹ̀ tirẹ̀ wá sínú ilé Ọlọ́run, wúrà àti fàdákà àti àwọn ohun èlò náà. 19Kò sí ogun mọ́ títí fún ọdún márùndínlógójì ti ìjọba Asa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.