2 Kronika 15:1
2 Chronicles 15:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ̀mí Ọlọ́run wá sórí Asariah ọmọ Odedi.
2 Chronicles 15:1 in English
2 Chronicles 15:1 · Berean Standard Bible
Now the Spirit of God came upon Azariah son of Oded.
Context
1Ẹ̀mí Ọlọ́run wá sórí Asariah ọmọ Odedi. 2Ó jáde lọ bá Asa, ó sì wí fún un pé, “Tẹ́tí si mi Asa, àti gbogbo Juda àti Benjamini. Olúwa wà pẹ̀lú rẹ, nígbà tí ìwọ bá wà pẹ̀lú rẹ̀. Ti ìwọ bá wá a, ìwọ yóò rí i ní ẹ̀bá ọ̀dọ̀ rẹ ṣùgbọ́n tí ìwọ bá kọ̀ ọ́ sílẹ̀, òun yóò kọ̀ ọ́ sílẹ̀. 3Fún ọjọ́ pípẹ́ ni Israẹli ti wà láì sin Ọlọ́run òtítọ́, àti láìní àlùfáà ti ń kọ́ ni, àti láìní òfin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.