2 Kronika 13:1
2 Chronicles 13:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní ọdún kejìdínlógún ìjọba Jeroboamu, Abijah di ọba Juda.
2 Chronicles 13:1 in English
2 Chronicles 13:1 · Berean Standard Bible
In the eighteenth year of Jeroboam’s reign, Abijah * became king of Judah,
Context
1Ní ọdún kejìdínlógún ìjọba Jeroboamu, Abijah di ọba Juda. 2Ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹ́ta. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ Mikaiah, ọmọbìnrin Urieli ti Gibeah.
Ogun wà láàrín Abijah àti Jeroboamu. 3Abijah lọ sí ojú ogun pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogun ogún ọ̀kẹ́ (400,000) ọkùnrin alágbára, Jeroboamu kó ogun jọ pẹ̀lú ogójì ọ̀kẹ́ (800,000) ọ̀wọ́ ogun tí ó lágbára.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.