2 Kronika 11:6
2 Chronicles 11:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bẹtilẹhẹmu, Etamu, Tekoa,
2 Chronicles 11:6 in English
2 Chronicles 11:6 · Berean Standard Bible
He built up Bethlehem, Etam, Tekoa,
Context
4‘Èyí ní ohun tí Olúwa wí. Ẹ má ṣe gòkè lọ láti lọ jà pẹ̀lú arákùnrin yín, ẹ lọ sílé, gbogbo yín, nítorí ti ìṣe mi nìyí.’ ” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n tẹ̀lé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, wọ́n sì padà sẹ́yìn láti yan lọ dojúkọ Jeroboamu. 5Rehoboamu ń gbe ní Jerusalẹmu ó sì kọ́ àwọn ìlú fún olódi ní Juda. 6Bẹtilẹhẹmu, Etamu, Tekoa, 7Beti-Suri, Soko, Adullamu, 8Gati, Meraṣa Sifi,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.