Native Bible

1 Thessalonians 2:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítòótọ́, ẹ̀yin ni ògo àti ayọ̀ wa.

1 Thessalonians 2:20 in English

1 Thessalonians 2:20 · Berean Standard Bible

You are indeed our glory and our joy.

Context

18Nítorí àwa fẹ́ wá sí ọ̀dọ̀ yín—àní èmi, Paulu, gbìyànjú ní ọ̀pọ̀ ìgbà láti wá, ṣùgbọ́n èṣù ú dè wá lọ́nà. 19Kí ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, tàbí adé wa nínú èyí tí a ó ṣògo níwájú Jesu Olúwa nígbà tí òun bá dé? Ṣé ẹ̀yin kọ́ ni? 20Nítòótọ́, ẹ̀yin ni ògo àti ayọ̀ wa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.