Native Bible

1 Corinthians 3:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ̀yin sì ni ti Kristi; Kristi sì ni ti Ọlọ́run.

1 Corinthians 3:23 in English

1 Corinthians 3:23 · Berean Standard Bible

and you belong to Christ, and Christ belongs to God.

Context

21Nítorí kí ẹnikẹ́ni má ṣe ṣògo nínú ènìyàn. Nítorí tí yín ni ohun gbogbo. 22Ìbá ṣe Paulu, tàbí Apollo, tàbí Kefa, tàbí ayé tàbí ìyè, tàbí ikú, tàbí ohun ìsinsin yìí, tàbí ohun ìgbà tí ń bọ̀; tiyín ni gbogbo wọn. 23Ẹ̀yin sì ni ti Kristi; Kristi sì ni ti Ọlọ́run.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.