1 Kọrinti 15:5
1 Corinthians 15:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àti pé ó farahàn Peteru, lẹ́yìn èyí, àwọn méjìlá.
1 Corinthians 15:5 in English
1 Corinthians 15:5 · Berean Standard Bible
and that He appeared to Cephas * and then to the Twelve.
Context
3Nítorí èyí tí mo rí gbà ṣáájú ohun gbogbo ní èmi pẹ̀lú ti fi lé e yín lọ́wọ́, bí Kristi ti kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wá gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ tí wí. 4Àti pé a sìnkú rẹ̀, àti pé ó jíǹde ní ọjọ́ kẹta gẹ́gẹ́ bí Ìwé Mímọ́ tí wí; 5àti pé ó farahàn Peteru, lẹ́yìn èyí, àwọn méjìlá. 6Lẹ́yìn èyí, ó farahàn àwọn ará tí o jú ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) lọ lẹ́ẹ̀kan náà; ọ̀pọ̀ nínú wọn wà títí fi di ìsinsin yìí, ṣùgbọ́n àwọn díẹ̀ ti sùn. 7Lẹ́yìn èyí ni ó farahan Jakọbu; lẹ́yìn náà fún gbogbo àwọn aposteli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.