1 Kronika 7:26
1 Chronicles 7:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Laadani ọmọ rẹ̀ Ammihudu ọmọ rẹ̀, Eliṣama ọmọ rẹ̀,
1 Chronicles 7:26 in English
1 Chronicles 7:26 · Berean Standard Bible
Ladan his son, Ammihud his son, Elishama his son,
Context
24Ọmọbìnrin rẹ̀ sì jẹ́ Ṣerah, ẹni tí ó kọ́ ìsàlẹ̀ àti òkè Beti-Horoni àti Useni-Ṣerah pẹ̀lú. 25Refa jẹ́ ọmọ rẹ̀, Resefi ọmọ rẹ̀,
Tela ọmọ rẹ̀, Tahani ọmọ rẹ̀, 26Laadani ọmọ rẹ̀ Ammihudu ọmọ rẹ̀,
Eliṣama ọmọ rẹ̀, 27Nuni ọmọ rẹ̀
àti Joṣua ọmọ rẹ̀. 28Ilẹ̀ wọn àti ìfìdíkalẹ̀ wọn ni Beteli àti àwọn ìletò tí ó yíká, Narani lọ sí ìhà ìlà-oòrùn, Geseri àti àwọn ìletò rẹ̀ lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Ṣekemu àti àwọn ìletò rẹ̀ ní ọ̀nà lọ sí Ayahi àti àwọn ìletò.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.